Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 20:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síbẹ̀síbẹ̀ ninú ogun mìíràn, tí ó wáyé ní Gátì, ọkùnrin títóbi kan wà tí ó ní ìka mẹ́fà ní ọwọ́ Rẹ̀ pẹ̀lú ìka mẹ́fà ní ẹṣẹ̀ Rẹ̀ (24) Mẹ́rìnlélógún lápapọ̀. Òun pẹ̀lú wá láti Ráfà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 20

Wo 1 Kíróníkà 20:6 ni o tọ