Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 20:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ẹ̀yìn èyí ni ogun bẹ́ sílẹ̀ ní Géṣérì pẹ̀lu àwọn ará Fílístínì, ní àkókò yìí ni Ṣíbékíà ará Húsà pa Ṣípáì, ọ̀kan lára àwọn ọmọ Réfáì, àti àwọn ará Fílístínì ni a sẹ́gun.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 20

Wo 1 Kíróníkà 20:4 ni o tọ