Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 19:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Hanúnì fi ipá mú àwọn ọkùnrin Dáfídì, fá irun wọn, wọ́n gé ẹ̀wù wọn kúrò ní àárin ìdí Rẹ̀, ó sì rán wọn lọ.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 19

Wo 1 Kíróníkà 19:4 ni o tọ