Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 17:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n sì ti ṣe láti ìgbà tí mo ti yan àwọn aṣájú lórí àwọn ènìyàn mi Ísírẹ́lì. Èmi pẹ̀lú yóò sẹ́gun gbogbo àwọn ọ̀ta yín.“ ‘Èmi sọ fún yín pé Olúwa yóò kọ́ ilé kan fún yín:

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 17

Wo 1 Kíróníkà 17:10 ni o tọ