Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 16:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó yan díẹ̀ lára àwọn ará Léfì láti máa jọ́sìn níwájú àpótí ẹ̀rí Olúwa, àti láti ṣe ìrántí àti dúpẹ́ àti láti yin Olúwa, Ọlọ́run Ísírélì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 16

Wo 1 Kíróníkà 16:4 ni o tọ