Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run, wá sínú àgọ́ ti Dáfídì ti pàṣẹ fún un, wọ́n sì gbé ọrẹ sísun àti ọrẹ ìdàpọ̀ kalẹ̀ níwájú Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 16

Wo 1 Kíróníkà 16:1 ni o tọ