Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 15:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì ránṣẹ́ pe Ṣádókù, Ábíátarì tí wọ́n jẹ́ àlùfáà, àti Úríélì, Ásáíà. Jóẹ́lì, Ṣémáíà, Élíélì àti Ámínádábù tí wọ́n jẹ́ Léfì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 15

Wo 1 Kíróníkà 15:11 ni o tọ