Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 13:13-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Kò gbé àpótí ẹ̀rí náà wá sí ọ̀dọ̀ ará Rẹ̀ ní ìlú ti Dáfídì dípò èyí, ó sì gbé e sí ẹ̀gbé, sí ilé Obedi-Édómù ará Gítì.

14. Àpótí ẹ̀rí Olúwa sì wà lọ́dọ̀ àwon ará ilé Obedi-Édómù ní ilé Rẹ̀ fún oṣù mẹ́ta, Olúwa sì bùkún agbo ilé àti gbogbo ohun tí ó ní.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 13