Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 11:44-47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

44. Úsíà ará Ásílérátì,Ṣámà àti Jégiẹ́lì àwọn ọmọ Hótanì ará Áróérì,

45. Jédíáélì ọmọ Ṣímírì,àti arákùnrin Jóhà ará Tísì

46. Élíélì ará MáháfìJéríbáì àti Jóṣáfíà àwọn ọmọ Élánámì,Ítímáì ará Móábù,

47. Élíélì, Óbédì àti Jásídì ará Mésóbà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11