Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 11:41-45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

41. Húríyà ará HítìṢábádì ọmọ Áháláyì.

42. Ádínà ọmọ Ṣísà ará Réúbẹ́nì, ẹni tí ó jẹ́ ìjòyè ará Réubẹ́nì, àti pẹ̀lú ọgbọ́n Rẹ̀.

43. Hánánì ọmọ Mákà.Jóṣáfátì ará Mítínì.

44. Úsíà ará Ásílérátì,Ṣámà àti Jégiẹ́lì àwọn ọmọ Hótanì ará Áróérì,

45. Jédíáélì ọmọ Ṣímírì,àti arákùnrin Jóhà ará Tísì

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11