Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 11:37-47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

37. Hésírónì ará KárímélìNáráì ọmọ Ésíbáì,

38. Jóẹ́lì arákùnrin NátanìMíbárì ọmọ Hágárì,

39. Ṣélékì ará Ámónì,Náháráì ará Bérótì ẹni tí ó jẹ́ áru ìhámọ́ra Jóábù ọmọ Ṣérúyà.

40. Írà ará Ítírì,Gárébù ará Ítírì,

41. Húríyà ará HítìṢábádì ọmọ Áháláyì.

42. Ádínà ọmọ Ṣísà ará Réúbẹ́nì, ẹni tí ó jẹ́ ìjòyè ará Réubẹ́nì, àti pẹ̀lú ọgbọ́n Rẹ̀.

43. Hánánì ọmọ Mákà.Jóṣáfátì ará Mítínì.

44. Úsíà ará Ásílérátì,Ṣámà àti Jégiẹ́lì àwọn ọmọ Hótanì ará Áróérì,

45. Jédíáélì ọmọ Ṣímírì,àti arákùnrin Jóhà ará Tísì

46. Élíélì ará MáháfìJéríbáì àti Jóṣáfíà àwọn ọmọ Élánámì,Ítímáì ará Móábù,

47. Élíélì, Óbédì àti Jásídì ará Mésóbà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11