Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 11:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àtijọ́, kódà nígbà tí Ṣọ́ọ̀lù jẹ ọba, ìwọ ni ẹni tí ó darí Ísírẹ́lì ní ojú ogun wọn. Olúwa Ọlọ́run rẹ sì wí fún ọ pé, ‘Ìwọ yóò sì jẹ́ olùsọ́ àgùntàn fún àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì, ìwọ yóò sì jẹ́ olórí fún wọn.’ ”

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11

Wo 1 Kíróníkà 11:2 ni o tọ