Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 11:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mẹ́ta nínú àwọn ọgbọ̀n (30) ìjòyè sọ̀kalẹ̀ tọ́ Dáfídì wá lọ sí orí àpáta nínú ìhò Ádúlámù; Nígbà tí àwọn ẹgbẹ́ Fílístínì sì dúró ní àfonífojì ní orí òkè Réfáímù.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11

Wo 1 Kíróníkà 11:15 ni o tọ