16. Ti Iddo, Sekariah; ti Ginnetoni, Meṣullamu;
17. Ti Abijah, Sikri; ti Miniamini, ti Moadiah, Piltai:
18. Ti Bilga, Sammua; ti Ṣemaiah, Jehonatani;
19. Ati ti Joaribu, Mattenai; ti Jedaiah, Ussi;
20. Ti Sallai, Killai; ti Amoku, Eberi;
21. Ti Hilkiah, Haṣhabiah; ti Jedaiah, Netaneeli;
22. Ninu awọn ọmọ Lefi li ọjọ Eliaṣibu, Joiada, ati Johanani, ati Jaddua, awọn olori awọn baba: li a kọ sinu iwe pẹlu awọn alufa, titi di ijọba Dariusi ara Perṣia.
23. Awọn ọmọ Lefi, olori awọn baba li a kọ sinu iwe itan titi di ọjọ Johanani ọmọ Eliaṣibu.