Nebusaradani, balogun iṣọ, si fi ninu awọn talaka ilẹ na silẹ lati mã ṣe alabojuto ajara ati lati ma ṣe alaroko.