O si ṣe, nigbati gbogbo awọn enia ti o wà pẹlu Iṣmaeli ri Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo awọn olori ogun ti o pẹlu rẹ̀, nwọn si yọ̀,