Gbogbo awọn ijoye si tọ̀ Jeremiah wá, nwọn bi i lere: o si sọ fun wọn gẹgẹ bi gbogbo ọ̀rọ wọnyi ti ọba ti palaṣẹ fun u. Bẹ̃ni nwọn dakẹ nwọn si jọ̃rẹ̀; nitori ẹnikan kò gbọ́ ọ̀ran na.