Arabia, ati gbogbo awọn ọmọ-alade Kedari, awọn ni awọn oniṣòwo rẹ, ni ọdọ-agutan, ati agbò, ati ewurẹ; ninu wọnyi ni nwọn ṣe oniṣòwo rẹ.