Kí inú àwọn orílẹ̀-èdè ó dùn,kí wọn ó máa kọrin ayọ̀,nítorí pé ò ń ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan láìṣe ojuṣaaju;o sì ń tọ́ gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ayé.