9. Àwọn ọmọ Israẹli ṣẹgun gbogbo ọba àwọn ìlú wọnyi: Jẹriko ati Ai, lẹ́bàá Bẹtẹli;
10. Jerusalẹmu ati Heburoni,
11. Jarimutu ati Lakiṣi;
12. Egiloni ati Geseri,
13. Debiri ati Gederi;
14. Horima ati Aradi,
15. Libina ati Adulamu;
16. Makeda ati Bẹtẹli,
17. Tapua ati Heferi;
18. Afeki ati Laṣaroni,
19. Madoni ati Hasori;
20. Ṣimironi Meroni ati Akiṣafu,
21. Taanaki ati Megido;
22. Kedeṣi ati Jokineamu, ní Kamẹli;
23. Dori, tí ó wà ní etí òkun; Goiimu, tí ó wà ní Galili,
24. ati Tirisa. Gbogbo wọn jẹ́ ọba mọkanlelọgbọn.