Má bú ọba, kì báà jẹ́ ninu ọkàn rẹ,má sì gbé ọlọ́rọ̀ ṣépè, kì báà jẹ́ ninu yàrá rẹ,nítorí atẹ́gùn lè gbé ọ̀rọ̀ rẹ lọ,tabi kí àwọn ẹyẹ kan lọ ṣòfófó rẹ.