36. Faniya, Meremoti, ati Eliaṣibu,
37. Matanaya, Matenai ati Jaasu.
38. Ninu ìdílé Binui: Ṣimei,
39. Ṣelemaya, Natani, ati Adaaya,
40. Makinadebai, Ṣaṣai ati Ṣarai,
41. Asareli, Ṣelemaya, ati Ṣemaraya,
42. Ṣalumu, Amaraya, ati Josẹfu.
43. Ninu ìdílé Nebo: Jeieli, Matitaya, Sabadi, Sebina, Jadai, Joẹli, ati Benaaya.
44. Gbogbo àwọn tí wọ́n fẹ́ obinrin àjèjì ni wọ́n kọ àwọn aya wọn sílẹ̀ tọmọtọmọ.