Wọ́n gbéra láti Efuraimu lọ sí àfonífojì náà,wọ́n tẹ̀lé ọ, ìwọ Bẹnjamini pẹlu àwọn eniyan rẹ.Àwọn ọ̀gágun wá láti Makiri,àwọn olórí ogun sì wá láti Sebuluni.