N óo mú kí àwọn tó ń ni ọ́ lára máa pa ara wọn jẹ:wọn óo máa mu ẹ̀jẹ̀ ara wọn, bí ẹni mu ọtí,gbogbo ayé yóo sì mọ̀ nígbà náà pé,èmi ni OLUWA, Olùgbàlà rẹ,Olùràpadà rẹ, Ọlọrun alágbára Jakọbu.”