Nítorí náà mo sọ àwọn olórí ibi mímọ́ mi di aláìmọ́,mo fi Jakọbu sílẹ̀ fún ìparun;mo sì sọ Israẹli di ẹni ẹ̀sín.”