Heṣiboni ati Eleale ń kígbe lóhùn rara,àwọn ará Jahasi gbọ́ ariwo wọn;nítorí náà àwọn ọmọ ogun Moabu sọkún,ọkàn rẹ̀ sì wárìrì.