Nígbà náà ni Jésù dúró níwájú Baálẹ̀ láti gba ìdájọ́. Baálẹ̀ sì béèrè pé, “Ṣe ìwọ ni Ọba àwọn Júù?”Jésù dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, nítorí tí ìwọ wí i.”