Nígbà tí Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì dé Kápánámù, àwọn agbowó-òde tọ Pétérù wá wọ́n sì bí i pé, “Ǹjẹ́ Olúwa yín ń dá owó tẹ̀ḿpìlì?”