Wọ́n dáhùn pé, “Mósè yọ̀ǹda ìkọ̀sílẹ̀. Ohun tí ọkùnrin náà yóò ṣe ni kí ó fún un ní ìwé ìkọ̀sílẹ̀, lẹ́yìn èyí, ààyè wà láti kọ obìnrin náà sílẹ̀.”