Gbọ́ ohun igbe àwọn olùṣọ́-àgùntàn;ògo wọn bàjẹ́;gbọ́ ohùn bíbú àwọn ọmọ kìnnìúnnítorí ògo Jódánì bàjẹ́.