Ìwọ bẹ ayé wò, o sì bomirin;ìwọ mú ní ọ̀rọ̀ púpọ̀.Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run kún fún omiláti pèsè ọkàn fún àwọn ènìyàn,nítorí ibẹ̀ ní ìwọ ti yàn án.