Kìkì èró wọn ni láti bì ṣubúkúrò nínú ọlá Rẹ̀;inú wọn dùn sí irọ́.Wọn ń fi ẹnu wọn súre,ṣùgbọ́n wọ́n ń gégùn nínú ọkàn wọn. Sela