Wòó, bí wọ́n ṣe ba ní bùba dè mí!Àwọn alágbára ń gbìmọ̀ lòdì sí miKìí se nítorí ìrékọja mi tàbí ẹ̀ṣẹ̀ mí, Olúwa.