Nígbà tí ìwọ bá yọìwọ yóò mú wọn dàbí ìnà ìléru. Olúwa yóò gbé wọn mì nínú ìbínú Rẹ̀,àti pé iná Rẹ̀ yóò jó wọn run.