Má ṣe jẹ́ kí ọkàn mi fà sí ohun tí ń ṣe ibi,Láti máa bá àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ búburúmá sì ṣe jẹ́ kí èmi jẹ́ àdídùn wọn.