Àwọn agbéraga ti dẹkùn sílẹ̀ fún mi àti okùn:wọ́n ti na àwọ̀n lẹ́bá ọ̀nà;wọ́n ti kẹ́kùn sílẹ̀ fún mi.