Obìnrin Rẹ yóò dà bí àjàrà rereeléso púpọ̀ ní àárin ilé Rẹ;àwọn ọmọ Rẹ yóò dà bí igi olífì tí ó yí tábìlì Rẹ ká.