Ìbínú Olúwa yóò sì tún ru sí Ísírẹ́lì a sì wí pé, “Nítorí tí orílẹ̀-èdè yìí ti yẹ májẹ̀mu tí mo fi lélẹ̀ fún àwọn baba ńlá wọn, tí wọn kò sì fetí sí mi.