Ẹ wá kánkán, gbogbo ẹ̀yin aláìkọlà láti gbogbo àyíká,kí ẹ sì gbá ara yín jọ yí káàkiri:Níbẹ̀ ní kí o mú àwọn alágbára rẹ ṣọkalẹ̀, Olúwa.