Nítorí náà, èyi ni ohun tí Olúwa wí:“Èmi yóò gbé ohun ìdènà ṣíwájúàwọn ènìyàn wọ̀nyí, àwọn bàbáàti ọmọ yóò jùmọ̀ ṣubú lù wọ́n,àwọn aládùúgbò àti ọ̀rẹ́ yóò ṣègbé.”