Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké,àwọn àlùfáà sì ń ṣe àkóso pẹ̀lú àṣẹ ara wọn,àwọn ènìyàn mi sì nífẹ̀ẹ́ sí èyí,kí ni ẹ̀yin yóò ṣe ní òpin?