40. Mákánádébáì, Ṣásíáì, Ṣáráì,
41. Ásárélì, Ṣélémíáyà, Ṣémáríàyà,
42. Ṣálílúmì, Ámáríyà àti Jóṣẹ́fù.
43. Nínú àwọn ìran Nébò:Jérélì, Mátítaíyà, Ṣábádì, Ṣábínà, Jádáì, Jóélì àti Bénáíáyà.
44. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ló fẹ́ obìnrin àjèjì, àwọn mìíràn nínú wọn sì bi ọmọ ní ipaṣẹ̀ àwọn ìyàwó wọ̀nyí.