Fáráò sì ránṣẹ́ pe Mósè ó sì wí fún un pé, “Lọ sìn Olúwa, kódà àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé lè lọ pẹ̀lú yín, ṣùgbọ́n kí ìwọ kí ó fi agbo àgùntàn àti agbo màlúù yín sílẹ̀.”