A kì yóò gbọ́ nípa rògbòdìyàn ní ilẹ̀ rẹ mọ́,tàbí ìdahoro àti ìparun nínú agbègbè rẹ,ṣùgbọ́n ìwọ yóò pe ògiri rẹ ní ìgbàlààti àwọn ẹnu bodè rẹ ní ìyìn.