Lótìítọ́ ìwọ yóò ké sí àwọn orílẹ̀ èdè tí ìwọ kò mọ̀àti orílẹ̀ èdè tí ìwọ kò mọ̀ ni yóò sáré tọ̀ ọ́ wá,Nítorí Olúwa Ọlọ́run rẹẸni Mímọ́ Ísírẹ́lìnítorí pé ó ti fi ohun dídára dá ọ lọ́lá.”