Àìsáyà 48:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
“Ẹ súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi kí ẹ sì dẹtí sí èyí:“Láti ìgbà ìkéde àkọ́kọ́ èmi kò sọ̀rọ̀ ní ìkọ̀kọ̀;ní àṣìkò tí ó sì ṣẹlẹ̀, Èmi wà níbẹ̀.”Àti ní àkókò yìí, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni ó ti rán mi,pẹ̀lú ẹ̀mii rẹ̀.