Èmi ti gbá gbogbo ìkùnà rẹ dànù bí i kùrukùru,àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ bí ìrì òwúrọ̀.Padà sọ́dọ̀ mi,nítorí mo ti rà ọ́ padà.”