Nínú ìfẹ́ a ó fi ìdí ìjọba kan múlẹ̀,ní òdodo ọkùnrin kan yóò jókòó lóríi rẹ̀—ọ̀kan láti ilé Dáfídì wá.Ẹni nní ti ìdájọ́ ń wá ẹ̀tọ́tí ó sì fi ìyára wá ohun tí í ṣe òdodo.