Ṣùgbọ́n àwọn ohun abẹ̀mí aṣálẹ̀ ni yóò gbé bẹ̀,àwọn ajáko yóò kún inú ilé wọn,níbẹ̀ ni àwọn òwììwí yóò máa gbéníbẹ̀ ni àwọn ewúrẹ́-igbó yóò ti máa bẹ́ kiri.