Wọn kò ní ṣeni lọ́ṣẹ́ tàbí panirunní gbogbo òkè mímọ́ mi,nítorí gbogbo ayé yóò kún fún ìmọ̀ Olúwagẹ́gẹ́ bí omi ti í bo òkun.